Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.
Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).
Dájúdájú, ẹni tó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.